Asake |
---|
![](//upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/f/fa/Asake_in_Terminator_music_video.png/220px-Asake_in_Terminator_music_video.png) |
Background information |
---|
Orúkọ àbísọ | Ahmed Ololade |
---|
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Mr. Money |
---|
Ọjọ́ìbí | 13 Oṣù Kínní 1995 (1995-01-13) (ọmọ ọdún 30) Lagos State, Nigeria |
---|
Irú orin | |
---|
Occupation(s) |
|
---|
Instruments | Vocals |
---|
Years active | 2018–present |
---|
Labels | YBNL, Empire |
---|
Ahmed Ololade
Listen tí wọ́n bí ni ọjọ́ kẹtàlá oṣù kìíní, ọdún 1995,[1] tí orúkọ ìnágìjẹ rẹ̀ ǹ jè Asake jẹ́ olórin Afrobeats láti orílẹ́ èdè Nàìjíríà.[2][3][4][5] Ó jẹ́ olórin lábẹ́ àkóso YBNL Nation.[6][7] Orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ ọ́ sí jẹ́ orúkọ ìyá rẹ̀.[8]
- ↑ Sare, Watimagbo (2022). "Asake Biography, Songs, & Albums". Allmusic. Retrieved 2023-06-01.
- ↑ https://punchng.com/olamide-inspires-me-with-his-knowledge-of-showbiz-asake/
- ↑ Asake, Ola. "Wave Asake Mp3". Naija Pickup (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Subeditor (20 August 2022). "'Mr Money' Asake: Biography, Education, Songs, Girlfriend, Net Worth and Achievement". NewsWireNGR (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-09-04.
- ↑ "Olamide inspires me with his knowledge of showbiz –Asake". Punch Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 3 June 2022. Retrieved 29 July 2022.
- ↑ Alake, Motolani (8 February 2022). "Olamide signs Asake to YBNL". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 29 July 2022.
- ↑ "American record label welcomes Asake to fold". The Nation Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 19 July 2022. Retrieved 2022-09-24.
- ↑ Sare, Watimagbo (29 September 2022). "YBNL's Asake Reveals How He Got His Stage Name". Allnews.ng. Retrieved 2022-09-29.