Zlatan | |
---|---|
![]() zlatan Ibile | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Omoniyi Temidayo Raphael |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Zlatan Ibile, Kapaichumarimarichupako , World President |
Ọjọ́ìbí | 19 Oṣù Kejìlá 1994 Lagos, Nigeria |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Instruments | Vocals, Drums |
Years active | 2014-Present |
Labels | Zanku Records |
Associated acts |
Ọmọ́níyì Tèmídayọ̀ Raphael (bí ní ọjọ́ kọnkọ̀dínlógún oṣù Kejìlá ọdún 1994), tí wọ́n mọ̀ ọ́ ní tiyì sí Zlatan Ìbílẹ̀, jẹ́ Rápà, Akọrin, Akọ-Orin, Olórin àti Oníjó Nàìjíríà láti Èkìtì,[1] Ijero local government area, Ìpínlẹ̀ Èkìtì.[2] Ó jẹ́ Olórí àti Olùdásílẹ̀ Zanku Records.[3] Ní ọdún 2014, ó gba ipò àkọ́kọ́ tí ilé-iṣẹ́ Airtel pàsè tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ One Mic talent show tí wọ́n ṣe ní ọdún 2014, Abéòkúta, Ìpínlẹ̀ Ògùn.[4]
Kó tó di ìparí ọdún 2018, Zlatan kọ orin sílẹ̀ tí ó pè ní Zanku", pẹ̀lú ijọ́ tuntun tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ orúkọ orin náà.[5] Ní ọjọ́ kẹ́ta oṣù kọkọ̀nlá ọdún 2019,Ó fi álíbọ̀bù àkọ́kọ́ rẹ̀ sílẹ̀ tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ ZANKU, tí ó túmọ̀ sí Zlatan Abeg No Kill Us.[6] Akọrin náà sọ wí pé ó wu òun láti di Agbábọ̀lù-Afẹṣẹ̀gbá ní ọdún 2020, pé kí í ṣe Olórin.[7]
Ọmọ́níyì Tèmídayọ̀ Raphael (bí ní ọjọ́ kọnkọ̀dínlógún oṣù Kejìlá ọdún 1994), tí wọ́n mọ̀ ọ́ ní tiyì sí Zlatan Ìbílẹ̀, jẹ́ Rápà, Akọrin, Akọ-Orin, Olórin àti Oníjó Nàìjíríà láti Èkìtì,[8] Ijero local government area, Ìpínlẹ̀ Èkìtì.[9] Ó jẹ́ Olórí àti Olùdásílẹ̀ Zanku Records.[10] Ní ọdún 2014, ó gba ipò àkọ́kọ́ tí ilé-iṣẹ́ Airtel pàsè tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ One Mic talent show tí wọ́n ṣe ní ọdún 2014, Abéòkúta, Ìpínlẹ̀ Ògùn.[11]
Kó tó di ìparí ọdún 2018, Zlatan kọ orin sílẹ̀ tí ó pè ní Zanku", pẹ̀lú ijọ́ tuntun tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ orúkọ orin náà.[12] Ní ọjọ́ kẹ́ta oṣù kọkọ̀nlá ọdún 2019,Ó fi álíbọ̀bù àkọ́kọ́ rẹ̀ sílẹ̀ tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ ZANKU, tí ó túmọ̀ sí Zlatan Abeg No Kill Us.[13] Akọrin náà sọ wí pé ó wu òun láti di Agbábọ̀lù-Afẹṣẹ̀gbá ní ọdún 2020, pé kò kí í ṣe Olórin.[14]
<ref>
tag; no text was provided for refs named :0
<ref>
tag; no text was provided for refs named :1
<ref>
tag; no text was provided for refs named :2
<ref>
tag; no text was provided for refs named :3
<ref>
tag; no text was provided for refs named :4
<ref>
tag; no text was provided for refs named :5
<ref>
tag; no text was provided for refs named :6