Burna Boy |
---|
![](//upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/e/ef/Burna_Boy_%28cropped%29.jpg/220px-Burna_Boy_%28cropped%29.jpg) |
Background information |
---|
Orúkọ àbísọ | Damini Ebunoluwa Ogulu |
---|
Ọjọ́ìbí | 2 Oṣù Keje 1991 (1991-07-02) (ọmọ ọdún 33) Port Harcourt, Rivers State, Nigeria |
---|
Irú orin | |
---|
Occupation(s) | |
---|
Years active | 2011–present |
---|
Labels |
Publishing:
|
---|
Damini Ebunoluwa Ogulu ( tí a bí ní ọjọ́ kejì oṣụ́ keje, ọdún 1991),[1] tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jé Burna Boy, jẹ́ olórin ti oríl̀-èdè Naijiria. [2][3][4]
Ó di gbajúgbajà lẹ́yìn tí ó kọrin "Like to Party", ní ọdún 2012, èyí tó wà nínú àwo-orin rẹ̀ L.I.F.E tó jáde ní ọdún 2013. Ní ọdún 2017, ó tọwọ́ bọ̀wé pẹ̀lú Bad Habits/ Atlantic Records láti máa lo ilé-iṣẹ́ wọn fi gbórin jáde. Àwo-orin rẹ̀ ẹlẹ́ẹ̀kẹta tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Outside jẹ́ ọ̀kan lára àwọn isé rẹ̀ tó lààmìlaaka.[5] Ní ọdún 2019, ó gba àmì-ẹ̀yẹ lọ́wọ́ 2019 BET Awards, All Africa Music Awards, Best World Music Album.[6][7][8][9]
- ↑ Ibile, Fagbo (3 October 2021). "Burna Boy's Biography". AllMusic.com. Retrieved 3 October 2021.
- ↑ "Africa's biggest music stars". edition.cnn.com. Retrieved 10 December 2020.
- ↑ "The 'African Giant' Challenging Musical Boundaries". theatlantic.com. 26 July 2019. Retrieved 27 December 2020.
- ↑ "Burna Boy leads Billboard top 15 Sub-Saharan Artists". m.guardian.ng. 6 June 2020. Retrieved 27 December 2020.
- ↑ Nick Duerden (19 July 2019). "How Burna Boy Became Nigeria's Surprise Success Story". Billboard. Archived from the original on 30 July 2019. Retrieved 28 July 2019.
- ↑ "2Baba Burna Boy and Others Win at AFRIMA 2019". ChannelsTV (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 24 November 2019. Archived from the original on 27 November 2019. Retrieved 24 November 2019.
- ↑ Damolo Durosomo (20 November 2019). "Burna Boy, Angelique Kidjo, Trevor Noah & More Earn 2020 Grammy Nominations". OkayAfrica. Archived from the original on 21 November 2019. Retrieved 20 November 2019.
- ↑ "GRAMMY.com". GRAMMY.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 27 November 2020.
- ↑ "Grammys 2021: Burna Boy win at music awards" (in en-GB). BBC News. 14 March 2021. https://www.bbc.com/news/world-africa-56393983.