Chinko Ekun | |
---|---|
![]() | |
Ọjọ́ìbí | Oladipo Olamide Emmanuel 13 Oṣù Kẹ̀sán 1993 Ikeja, Lagos State, Nigeria |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Obafemi Awolowo University |
Iṣẹ́ |
|
Musical career | |
Irú orin | Hip hop |
Instruments | Vocals |
Years active | 2011–present |
Labels | Dek-Niyor Entertainment |
Associated acts | |
Oladipo Olamide Emmanuel (tí wọ́n bí ní 13 September 1993), tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ sì jẹ́ Chinko Ekun, jẹ́ olórin àti akọrin sílẹ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè látiObafemi Awolowo University.